GON-GO SO: Ijoba Gomina Ajimobi bi ile igbohun safefe Ayefele wo n’Ibadan
Ijoba Ipinle Oyo eyiti Gomina Abiola Ajumobi n se agbateru re ti fi ero katakata bi ile igbohun safefe ogbohuntarigi olorin ni, OgbeniYinka Ayefele ti a mo si Fresh FM wo ni agbegbe Challenge ni oluulu ijoba ipinle naa ti i se Ibadan.
Eleyi waye ni kutu owuro Ojo isinmi, Ojo kokandinlogun osu Kejo odun ti a wa ninu re bayi.
Ilese igbohun safefe ohun ni aami ti wa lara re fun igba die eleyi to fa ki Ogbeni Ayefele gbe ijoba ipinle naa lo si ile ejo lati dawo igbese ohun duro sugbon ti ko so eso ri o fe. (The station had been marked for demolition but Ayefele felt aggrieved and approached the court for its stoppage which did not yield his desired interest.)
L’akoko iroyin yii l’owuro ojo isinmi, ile naa ti di bibiwo pelu ero katakata ti a mo si budosa (As at the time of filing this report on Sunday morning, the radio station was being demolished.)
Ogunlogo awon omo ogun pelu ihamora ni won pese aabo fun awon osise ijoba ti won bi ile naa wo eleyi ti ko fun enikeni ni anfaani Latin da a duro. (There was a huge presence of security agents, armed to the teeth which made it impossible for anyone to attempt to stop the demolition).
Ko han gbangba idi pataki ti ile ohun fi di bibi wo sugbon o se e se konise pelu oro eto oselu ni ipinle naa. (It was not clear the rationale behind the demolition but may not be unconnected to power play in that state).